*Yoo ko eyo kan si Katsina
to je ilu re naa
Nibayii, ijoba apapo ti
setan lati se idasile ibudo imo ero igbalode ayarabiasa, ICT, siluu Ibadan nile
Oluyole, Oro yii ni minisita fun eto ibanisoro, Ogbeni Bayo Shittu so di mimo
nibi abewo re si ile ise ti n ko ero igbalode wole, Zinox Group, to kale siluu Eko.
Minisita ni sise idalesile ibudo imo ero igbalode yii yoo tun bo ran eto oro aje wa lowo nitori wi pe, imo ero igbalode je oja kan ti ko le kuta laelae. Yato si ilu Ibadan, minisita tun menu ba Kastina gege bi ibudo keji ti idalesile ibudo imo naa yoo ti gbe lale wu bi osumare.

“Imo ero ICT je orisii imo
eto oro aje kan ti kii ja ni kule bi epo robi tabi eto ogbin. Imo ero komputa
igbalode ICT tun je opa kutele fun idagbasoke ilu eleyii ti ko ye ka foju para
re. Ti ijoba ba le gbaruku ti i, ohun ti o ma mowo wole nigbogbo igba ni,"
Ogbeni Bayo se alaye bee
Alaga ile ise Zinox naa ko
sai fesi si oro minisita, o ni ile ise awon setan lati se gbogbo iranwo ti
minisita ba beere fun. A ti wi pe, ko si ohun ti won fe lati odo awon ti awon
ko ni pase lati ri daju wi pe erogba ijoba to wa lode yii kese jari nipa imo
ero komputa.
0 comments:
Post a Comment