*Isele naa farape ti
Awujale tile Ijebu
Oba Sikiru Adetona,
Awujale tile Ijebu, eni ti won bi lojo kewaa osu karun-un odun 1934 gori ite
awon baba re lojo keji osu kerin odun 1960 leni odun merindinlogbon (26),
eleyii ti n se eni ojo ori re kere julo lati joba nile Yoruba.
Nibayii, Obi Chukwuka Noah
Akaeze I, eni odun metadinlogun (17) ti gori ite awon babanla baba re gege bi
eni ojo ori re kere ju lo lati joba ni gbogbo ile Naijiria.
Obi ni won pe wale lati
ile Biritiko nibi to ti n kawe lowo lati wa joba le awon eniyan Ubulu-Uku to wa
ni ipinle Delta lori. Eleyii lo waye leyin ti awon ajinigbe kan seku pa baba re
to je oba tele ni ibere osu kinni odun taa wa ye.
0 comments:
Post a Comment