Leyin ojo to ro niluu Port Harcourt, to kale si ipinle Rivers ni kopekope yii, agbara ko je ki awon moto o rin geere mo loju ona a ti gba lo siluu Aba pelu bi omi se kun gbogbo oju titi.
Lati bi ose kan ni isele yii ti n waye, ko si dabi e ni wi pe irorun ti n deba awon awako oju ona naa rara.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment