Smiley face

Awon omo ologun Naijiria so oku awon omo Boko Haram di saara

  
Awon omo ologun Naijiria fakoyo pelu bi won se rolu ibuba awon omo Boko Haram to wa ni abule Alajeri to kale si Ijoba Ibile Guzamala to wa nipinle  Borno. Nibi ti won ti ran aimoye awon omo alakatakiti Boko Haram sorun osan gangan

 



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment