Smiley face

IWE IROYIN OWURO ose yii n gbona felifeli

Idajo iku Reverend King
di ebo si Ambode lorun
* Se ki gomina bu owo lu idajo naa ni?

Tani Falae se?
Awon soja tun doju ibon ko o

Awon ojogbon fi oye dokita da Tinubu lola


Emi sofo nibi rogbodiyan Mile 12


N'Ikorodu, awon ajinigbe ji akekoo meta gbe nileewe
* Won n beere fun ogun milionu lori omo kookan


Owo Abacha: Ile ejo pe Obasanjo ati Jonathan nija


Oluyole mi titi, ADETUNJI di Olubadan
* E wo ise Olorun: Adetunji se telo ri
* Eleyinju aanu ni oba tuntun
* Seriki ko yoju sibi iwuye

Odun kesan-an leyin
iku Kola Olawuyi

Buhari ki Obasanjo ati Baba Adeboye
ku oriire ojo ibi

IROYIN OWURO ose yii n gbona felifeli. Ogorun naira pere ni. Beere lowo fendo re.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment