Smiley face

Iwe IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo



Ija lobaloba gba eburu yo
* Awon agbaagba Ogun dide si laasigbo aarin Awujale ati Alake
* Oba Adetona ni Oba Gbadebo n doju ti ilu re
* Alake ni oun kii segbe Awujale
* Alaafin ni oun lolori gbogbo oba
* Orangun ni Okanbi nikan ko Oduduwa bi
 
Awon iyaloja n beere eto won
lowo ijoba egbe APC

Awon Ijebu kii se omo Oduduwa – Adebowale


Buhari toro aforijin lowo omo
Naijiria latari ina elentiriki to daku
* “Falala ni awon eniyan yoo ma gbadun
ina elentiriki lati ose yii lo” - Lai Muhammed


Ija ti ko nidii ni awon oba n ja
– Alagba Gbenro

Oba Akiolu kan saara si Ambode
lori awari awon omo ti won


Awon ota mi lo maa sewon – Doyin Okupe

Awa ko da osise irinwo duro
– Ileese momamona

Jegudujera: Ile ejo siwe esun Saraki lakotun

Kasiimu olokada gbe ipo
kinni ni Yunifasiti Osun

Molebi mi
ko tii pinnu
ohun ti a fe
se lori fiimu
baba mi
– Omo Ade Love

Omo Baba Sala gbe orin
apanilerin-in jade

Aye dorikodo, eleegun n jo hip hop


Rogbodiyan Mile 12 tun fe gba ona miran yo
* Owo te awon ologun ayederu


...Won fi ibon ko ifun omo ileewe jade ni Mile 12
*Oba Akiolu fara mo aba Ambode lati gbe oja Mile 12 kuro

Iji nla ja nile igbimo asofin ipinle Ondo

A o reeyan
wa gba owo
osu to le ni
N2.29bn
– Kemi Adeosun

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment