*Awon iyaloja n beere eto
won lowo ijoba egbe APC
Oloye Folasade Tinubu-Ojo |
"Ise kekere ko ni
awon egbe iyaloja se ni akoko idibo iyansipo ijoba to wa lode yii. Awon Yooba
si bo, won ni eni to ba se nidi pepe dandan ni ko je nidi pepe. Ko dara to bi
ijoba to wa lode ko se ri ti wa ro. Won ko tile fi wa sinu awon eto won kankan,
eleyii to kudiekaato," Folasade se alaye re bee.
Oloye Folasade ko sai tun
soro ba ipo re gege bi olori awon iyaloja ati bi o se je omo okan pataki ninu
awon agba egbe ti n se ijoba lowo.
"Tori wi pe mo je omo
Tinubu ko ni ki n ma se ojuse mi gege bi asaaju. Asaaju ni mi, mo si gbodo se
bi asaaju fun awon eniyan mi. Ero ati ife won si gbodo di mimuse fun mi. Eleyii
ko so wi pe mo tako egbe APC, ti egbe APC la n se.
To ba di lola, awon naa ni
a ma se atileyin fun," Folasade fi alaye e gunle bee niluu Abuja.
0 comments:
Post a Comment