Smiley face

E dakun, talo leru were?

Oko awon Hausa mola yii ni awon kan ri loju titi marose Eko si Ibadan. Didi iru eru bayii lewu, o si le fa ijamba oko. Mo nigbagbo wi pe, won yoo pada ko sowo awon eso oju ona ni.

A bi eyin o ri wi pe, nnkan ju nnkan lo?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment