Smiley face

Omotanwa gbayi: Omo olojo ibi gbeye

Orekelewa, okan pataki ninu awon ololufe OlayemiOniroyin, ti won fi gbogbo ka iroyin wa, Omidan Omotanwa, se ojo ibi lonii.

Ka ma paro, ninu eye, eye bi okin sowon nigbo. Omonakoyeri, oba eye alarambara aso oge lagba ninu ewa. Ninu awon omidan asiko yii, Omidan Omotanwa lewa, bakan naa lo tun fiwa omoluabi sikeji ara.
Okan ninu awon oniroyin wa ti le foro wa Omidan naa lenu wo, lati mo bi inu re se dun to pelu bo se le lodun. Abo iroyin naa re e:
 Oniroyin: Kini oruko yin ni kikun?
Omo olojo ibi: OMOTANWA OLAIDE Anytiwa
Oniroyin: Yoo ti to igba wo tee ti n ka Olayemi Oniroyin?
Omo olojo ibi: O ti se die o. Gbogbo igba lemi ma n wa si ori Olayemi Oniroyin lati ka awon iroyin to ni i se pelu oro oselu ati awon ilumooka lagbo amuludun.
OMOTANWA OLAIDE Anytiwa
Oniroyin: Oni ni ojo ibi yin, bawo ni inu yin se dun to?
Omo olojo ibi: Inu mi dun lati ri ojo toni, mo si tun gbadura ki tun se opolopo laye ninu ola ati idera.
Oniroyin: E je orekelewa obirin, ki ni asiri ewa yin?
Omo olojo ibi: Gbogbo obirin lo rewa gege bi iseda onikaluku. Bo se wu Olorun ni i sola. Sugbon nipa temi, mo gbiyanju lati se itoju ewa mi nipa sise aponle fun ara mi.
Oniroyin: Bawo?
Omo olojo ibi: Nipa ounje jije ati ipara lilo.
Oniroyin: Iru ipara wo leyin lo ati ounje te e n je?
Omo olojo ibi: Mo feran eso jije ati ewebe pupo. Ipara mi ko si yato si iru ipara ti gbogbo eyan ati eyin lo. (Erkk)
Oniroyin: (Erkk) Bawo le se mo ipara temi n lo? Adiagbon ati ori lemi lo.
Olojo ibi: Adiagbon ati ori gan-an lemi lo. (Erkk)
Oniroyin: Awon nnkan wo le fe ati eyi ti e korira?
Omo olojo ibi: Mo feran olotito eniyan. Mo si korira iro ati iyanje.
Oniroyin:Ti awon eniyan ba fe ki yin, nje e e le fun wa ni nomba ago yin?
Omo olojo ibi: Ko buru! Nomba mi ni: 08039284605 BBM: 5929FB8D
Oniroyin: Ti mo ba fun yin ni anfaani lati ki awon to ba wu yin, awon wo niwon yoo je?
Omo olojo ibi: Lakoko na, mo fe dupe lowo Olorun Oga ogo, Olupari-ola, Oba ti n gbeni lojo gboggbo. Olu ti n dara si mi nigba gbogbo.

Bakan naa ni mo fe ki awon ore mi pata nile ati loke okun.
Awon bi Muinat Olakiitan, eni ti ojo ibi re bo si April 06. Omolara Lolade, eni ti ojo ibi ti e naa bo si April 05, Abimbola Junaid, Iro Ayo Photography, Damilola, ati eniyan mi pataki, Asiwaju Wole Papa, mo nife re ju.

Mo tun dupe lowo gbogbo awon ore mi patapata ti mi o le daruko tan. Mo si n gbadura wi pe, ayo ko ni tan ninu aye gbogbo wa o. Ase.
Anytiwa. Ope lo jasi
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

4 comments:

  1. Im not surprised seeing everyone celebrating the damsel and this is the result of her act of being modest. Omotanwa, Eniola, Olaide Abefe, long may you live. HBD

    ReplyDelete
  2. Im not surprised seeing everyone celebrating the damsel and this is the result of her act of being modest. Omotanwa, Eniola, Olaide Abefe, long may you live. HBD

    ReplyDelete
    Replies
    1. MO dupe fun olorun to so MI di asko yin, to tun fun MI ni ore ofe LA se iranti ojo ibi MI, ope MI keji lo si odo awon obi MI nitori ti ko ba si awon ni Eni MO Eni to je OLAIDE, MO tun dupe ni owo awon ore MI fun ife ti won fi han si. MO dupe ni owo egbon olayemi Oniroyin fun ife ti won ni si MI lati ojo ti MO ti MO won ni won ti se dada si MI, ile ise yin a ma lo soke, eledua ko ni gbagbe yin.. MO WA pari ope MI si odo eyan MI, Eni MI pataki Asiwaju wole papa fun ife ti o ni si MI, e se gan ni.. Mi o ni Jo ara MI loju, MI o ni fi igberaga sayo. Eyin ololufe ti e fi ateranse si MI, MO dupe gan ni. Ikan ire ko ni tan Nile WA, e seun... Ire oooooo

      Delete
  3. https://www.facebook.com/groups/letakanako/permalink/1165409960176978/?comment_id=1165869750130999&notif_t=group_comment_follow&notif_id=1459770607960011

    ReplyDelete