Smiley face

Wemba ku nibi to ti n korin

Won ti ni iku omi ni pomuwe lodo. Sebi iku akikanju mbe loju ogun. Ogbontarigi akorin bi eni layin omo ilu Togo, Papa Wemba ti koja lo sorun bayii.

Baba eni eni odun merindinlaadorin (66) lo subulule nibi to ti n korin ni Festival des musiques urbaines d'Anoumabo (FEMUA) ni Abidjan, Cote d'Ivore lonii ojo kerinlelogun osu kerin odun 2016. Won sara gbe digbadigba lo si osibitu, sugbon ki won to de ile iwosan, nnkan ti baje, Wemba ti lo.

Ki Oluwa forun ke e!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment