Pelu awon iroyin orisiirisii to n jade lojoojumo nipa awon okunrin ti won fi tipatipa ba awon omobirin lajosepo,
Senator Florence Ita-Giwa ni o ye ki won ma ge nnkan omokunrin awon odaran ti won ba mu yato si ogba ewon ti won ju won si.
O ni eleyii yoo je bi eko nla fun awon ti won gbadun iru iwa ibaje bee.
Idahun nibi : YORUBA DUN
0 comments:
Post a Comment