Smiley face

Won ti bu erupe soju Alamieyeseigha nipinle Bayelsa

Won ti bu erupe soju Alamieyeseigha nipinle Bayelsa
Olayemi Olatilewa

Sebi won ni ko si eni ti ko ni ku, ko si seni ti oko baba re ko ni digboro.



Gomina ipinle Bayelsa tele, Diepreye Alamieyeseigha, ti pada wo kaa ile sun lojo Satide to koja yii [08-04-16] ni
Amassoma to wa nipinle Bayelsa.
Alamieyeseigha lo dagbere faye leni odun mejilelogota (62) lojo kewaa osu kewaa odun 2015.

Ti e ko ba gbagbe, oloogbe yii lo sa mo awon Oyinbo lowo nipa mimura bi obirin lodun 2005, leyin ti won fi esun kan wi pe, o ko £1.8m je eleyii to je owo ilu.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment