Enu ti igbin fi bu orisa, o ti pada lo fi ẹnu naa gbolẹ. Amugbalegbe nipa eto iroyin fun Goodluck Jonathan nigba isejoba re, Doyin Okupe, ti lo tori aforiji lowo Ebora ilu Owu, Oloye Olusegun Obasanjo, pelu bo se yaju si Ẹbọra ilu Owu nigba ti agbara si wa lowo oga re Jonathan.
Ohun ti Doyin Okupe so ni yii nisale pelu awon foto ibi to ti dobale gbalaja
Ohun ti Doyin Okupe so ni yii nisale pelu awon foto ibi to ti dobale gbalaja
Awon foto yii je PremiumTimes
0 comments:
Post a Comment