Enoch Durotoye |
Mo ti mọ Ogbeni Enoch Durotoye o se diẹ, yato si wi pe won jẹ Alufaa, oludanilekọọ pataki to kun fun arogun ati arojinlẹ ogbon ni won se. Orisiirisii akawe ati afiwe pelu ọgọọrọ apẹrẹ lo maa sodo sinu awon alaye waasu won. Awon nnkan bayii ma n je ki idanilẹkọọ won moyan lori pupọ ju.
Mo ti kan si won boya idanilẹkọọ ori foran tijade nipa awon ogbon merin ti won se alaye re soke yii, won si ti fi damiloju wi pe ko ni pẹ jade.
To ba ti jade, eyin naa yo ni anfaani lati gbọ ọ.
E ku oju lona fun idanilẹkọọ nla!
0 comments:
Post a Comment