Àwọn kan jókòó, àwọn kan dúró. Wọn yẹ àwọn kan sí ní árà ọ̀tọ̀, nígbà tí àwọn kan kò rí àyèsí gba. Wọn fi ìwé pé àwọn kan, nígbà tí àwọn kan...
Read More
Home / Oro Isipaya
Showing posts with label Oro Isipaya. Show all posts
Showing posts with label Oro Isipaya. Show all posts
Báyìí ni Ìyá Dare onigbin ṣe pàdé gómìnà, kositọma rẹ àtijọ́
"Mo má ń sọ fún àwọn ènìyàn wí pé Kositọma mi àtijọ́ ni gomina ṣùgbọ́n wọn kì í gba mi gbọ - Ìyá Dare onigbin ni Owena. Ó ti pe tí Ìyá...
Read More
Kò sí ìgbà táa dásọ tá rilẹ fiwọ́
Enikan ra motor lónìí , bóyá lẹ́yìn ọdún márùn-ún tàbí mẹ́wàá ni Èdùmàrè to gbọ́ àdúrà rẹ. Ìwọ náà ra, adùn ibẹ ni wí pé, motor àsìkò ni ti ...
Read More
Ọmọbìnrin to bọ lọ́wọ́ cancer tí gbé ìgbà ọpẹ
"Ni iru àkókò yìí lodun tó kọjá, mo sebi ohun tó kàn fún mi ní ikú. Ṣùgbọ́n ikú kò wù mú kú. Ara ń ní mi, àìsàn jẹjẹrẹ kò jẹ ń gbádùn, ...
Read More
Mo kò sọ́wọ́ Taju l'Ayẹyẹ n'Ibadan
Àwọn tí ènìyàn ń ro wí pé yóò nira fún láti wọ ìjọba ọrùn lè padà jẹ ẹni àkọ́kọ́ ti yóò wọlé. Nígbà tí àwọn ènìyàn mímọ́, tí a lérò wí pé w...
Read More
"Ọlọ́run Adeboye fi Ibẹrin pẹgan mi rẹ - Ẹri láti ìjọ RCCG
Ọmọbìnrin to tí ń woju Ọlọ́run fún ọmọ fún àìmọye ọdún padà wá jẹri níwájú Olúwa fún Ibẹrin (ọmọ mẹ́rin lẹẹkan náà). Ẹri yìí wáyé nínú ìpàd...
Read More
Ohun tí mo rí níbi mo ti ń rin gbéregbère kiri
Àwọn ọ̀rọ̀ ìyànjú yìí ni mo bá pade níbi mo ti ń rin gbéregbère kiri orí ayélujára. Mo rò wí pé ẹ má nifẹ rẹ
Read More
Ẹ wá wo ohun tí wọn ni kọ seese
Kini wọn ni kó seese nínú ayé rẹ? Kini ohun tó mú ọ sọ ìrètí nù? Edumare yóò mú ọ pàdé ìyanu rẹ lọjọ kan. Má sọ ìrètí nù!
Read More
Aṣọ ṣe koko ṣùgbọ́n imo ṣe pàtàkì jù lọ
Má gbé ìgbé ayé rẹ báyìí. Gbìyànjú, ri dájú wí pé, ó ń ṣe alekun imo rẹ lojoojumo. 📙 📙 📖
Read More
Àwọn ènìyàn ta padà nígbà tá ń gòkè, le pada wúlò ta bá ń sòkalẹ̀ bọ̀
Má gbegbe awon olóore rẹ nígbà tó kéré. Ma seranti awon eniyan ti won dúró tì ọ nígbà tí kò sì ohunkóhun lọ́wọ́ rẹ nígbà to ba gòkè. Awon Y...
Read More
Ore ibeta fun enikan soso
Ire ayo tí ẹ náà ń bọ̀
Read More
Àwọn abiyamọ ni eléyìí wá fun
Ẹ má fi ọmọ yín obirin ti ọkùnrin kankan, yala ọrẹ tàbí ìbátan. E máa sọ́ ọmọbìnrin yín nípa ibi tó ń jẹ̀ sí. E ma je ki ẹnikẹ́ni fọwọ́ kan...
Read More
Orisi ewe meji to le yi ipo yin pada si rere
Kosi ohun kan ti a fe se atunse re ninu igbesi aye wa ti a ko le dogbon si. Bi ko tile bo soju ȩ tan, yoo yato si bo ti wa tȩlȩ to je ipo...
Read More
Ile aye, ile asan! Akawe oro nipa gomina Taraba tele baniyan leru
E je ka ma se pelepele laye, nitori ko seni to mole ti yoo mola. Kosi ohun taa mu wa sile aye, ko si sohun taa mu lo sorun. Ile aye ile ...
Read More
Ire a ma foju jo ibi: Itan isele gidi oga ile ise Airtel
Irin ajo eda wa lowo Olorun oba. Eda kankan ko si mo ile ti yoo mola. Sugbon nipa aforiti, emi isin tooto, igbagbo, akikanju, jije ol...
Read More
Bayii ni Edua oke se yii igbe aye Attai @Dacosta9110 pada
Kosi ohun ti Eledumare oba ko le se. Oba to n pabida sobi dire. Okunrin kan ti n sise nile epo lodun 1999 ti wa di oga nile ise...
Read More
"Onigbagbo ti ko le fedefo dabi aro elese kan" - Paito Wa lo so bee
Gbajugbaja oniwaasu ede Yoruba lori telifisan, Paito Gbade Ogunlana ti gbogbo eniyan mo si Paito Wa so wi pe, onigbagbo ti ko ba ki n fe...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)