Fayose gbe awon ode ibile dide lati koju awon Fulani darandaran Ola Daviva 5/24/2016 11:50:00 am Iroyin Ipinle , Oro Oselu Edit Leyin ikolu awon Fulani darandaran nipinle Ekiti, Gomina Fayose ti gbe awon ode ibile dide pelu atileyin to nipon lati koju awon Fulani darandaran. Awon kan ni igbese Fayose le da wahala nla sile laipe. Kini ero ti yin? Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Ola Daviva RELATED POSTS Fayose gbe awon ode ibile dide lati koju awon Fulani darandaran Reviewed by Ola Daviva on 5/24/2016 11:50:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment