Hubert Ogunde Ko ̀ si ́ bi ́ a s ̣ e fe ̣ ki ́ Ì ba ̀ da ̀ n la ́ i ̀ me ̣́ nu ba àru ̀ n Ìba ̀ da ̀ n; sebi ́ wo ̣́ n...
Read More
Home / Iroyin Ipinle
Showing posts with label Iroyin Ipinle. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Ipinle. Show all posts
Kini wọn pé gbegiri atewedu nIbadan?
Ti Ọlọ́run bá ṣe ìyanu fún ẹ to bá wọ ìlú Ibadan. To ba fẹ jẹ amala, tí wọn ba bèèrè wí pé irú ọbẹ̀ wo ló fẹ́. Má sọ wí pé, "Ẹ fún mi ...
Read More
Ekiti nìkan lè tí lè jẹ irú ayé báyìí
Fresh Iyan Fresh Ẹmu.... Orí ìyá mi ooo
Read More
Kini yoo sele ti Ambode ba le awon danfo wole nipinle Eko?
Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti fi da awon olugbe ipinle re loju wi pe, ijoba oun si wa lori wi pe, awon danfo akero ni...
Read More
Fasola se abewo awon akanse ise ti n lo lowo nipinle Ekiti
Ipinle Ekiti ni Fasola bale si lonii gege bi minisita ise ode, ilegbe, ati monamona lati se abewo si awon akanse ise ti n lo lowo nipinl...
Read More
"Ko ni daa feni to fi iru adanwo yii kan ipinle Ekiti" Ta lo so bee?
Okunrin kan ti oruko re n je Precious Eze lo fi epe ranse feni to fi iru adanwo bayii kan ipinle Ekiti. O ni nigba ti awon ipinle yoku ...
Read More
E wa wo aye olopaa l'Eko Ambode
Awon olopaa yii lagbo wi pe won seku baba agbalagba kan nibi won ti n gbiyanju lati mu awako danfo kan
Read More
Ènìyàn mé̩rin pàdánù è̩mí lé̩yìn tí wó̩n mu Ògógóró ní il̀lú Abeokuta
- Kehind Oladeji Kò dín ní ènìyàn mé̩rin tí wó̩n ti pàdánù è̩mí wo̩n léyìn tí wó̩n mu o̩tí ògógóró ní ìlú...
Read More
Baba Kemi Olunloyo tun ti soro leyin leta to jade laaro oni
Ti e ba n fi okan ba awon iroyin ti n jade lataaro bo. Ni aaro yii (08/07016) ni atejade kan jade eleyii ti a gbo wi pe o ti owo Victor ...
Read More
Won ti yinbon pa asofin ipinle Oyo
Gideon Aremu, ti n soju ekun Orelope labe asia egbe oselu Labour ni awon ti fi ibon pa lale ana (01/07/06) nigba to n pada sile re to wa...
Read More
Fayose gbe awon ode ibile dide lati koju awon Fulani darandaran
Leyin ikolu awon Fulani darandaran nipinle Ekiti, Gomina Fayose ti gbe awon ode ibile dide pelu atileyin to nipon lati koju awon Fulani d...
Read More
Eto ọrọ ajẹ to dẹnukọlẹ ti se akoba fun awon asẹwo
Awon Yoruba bọ, won ni arun ti n se abọyade, gbogbo ọlọya pata ni i se. Eto ọrọ aje Naijeria to denukọle ti se akoba fun awon asewo onin...
Read More
Yegede! Won ti sawari epo robi nipinle Eko Ambode
Ori ire ti wọ ilu Eko pelu bi ile ise Yinka Folawiyo Petroleum Company Limited se se awari epo robi ni agbegbe Badagry to wa ni ipinle E...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)