Smiley face

Ijoba Ibile Ado Odo/Ota n reti Adewale Dada

Adewale Dada Thegood
Nibayii, Adewale Dada Thegood, gbajugbaja sorosoro ori afefe, ti fi ero re han lati dije fun ipo alaga Ijoba Ibile Ado Odo/Ota, ipinle Ogun labe asia egbe onigbale ti a mo si APC.

A fi bi eni wi pe awon ololufe Alao omo oloti Ota tile ti n reti re lati kede erogba re pelu bi opolopo won se sugba re lori igbese tuntun naa.

Thegood to se idasile ede asa "4+4" ti opolopo n lo nigba ipolongo eto idibo Gomina Ibikunle Amosun ti fi da awon ololufe re loju wi pe, oun ko ni ja ireti ati ife ti awon eniyan ni si i kule laelae.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment