Smiley face

Iya Rashidi Yekini agbaboolu n beere fun aanu

Alhaja Sidikat Yekini ni yii to je iya to bi gbajugbaja akoni ere ori-odan, Rashidi
Yekini. Buredi ati Pure Water ni iya naa ta bayii lati ri ounje je sikun.

Ti e ko ba gbagbe,Rashidi Yekini naa ni opolopo ipenija to ni i se pelu isuna owo, lai si oluranlowo fun un, ko to di wi pe o jade laye pelu opolopo inira ati ibanuje.

Aimoye eniyan ni won si n da awon ijoba lebi bi won se dagunla si akoni to lo ogbon ati ebun re fun idagbasoke ilu Naijiria.

Iya Rashidi n farugbo ara sise, eleyii ti ko si ye ko je bee rara. Se ijoba ko tun ni se ohunkohun ni?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment