E wo ara ti Yinka Ayefele n da Olayemi Oniroyin 5/07/2016 10:07:00 am Amuludun , Foto Edit Yinka Ayefele O ti daju gbangba wi pe ki i se orin nikan ni Yinka Ayefele le ko, omokunrin olorin emi naa tun un dara nile idana. Eleyii ni Oba Tungba se nigba ti n se efo rorowo to je oje kan pataki niluu Ekiti nibi ti agba olorin naa ti wa. Oya, eyin naa e wo oju obe ke e muyan Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS E wo ara ti Yinka Ayefele n da Reviewed by Olayemi Oniroyin on 5/07/2016 10:07:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment