Smiley face

IYO [@OfficialIyo] dalara gbayida


Iyo

Kosi eda ti ko ni fe ki Edua oke f'IYO saye oun. Oun gbogbo to ba si ti niy kii baj. j ay lonii jẹ pẹlu bi IYO, ogbontarigi akorinbirin, orekelẹwa apede gbayi, akin-ọmọ ti n korin bi ẹni layin se le lọdun lonii ọjọ karun-un osu karun-un odun (05-05-16). 

Bi o tilẹ jẹ wi pe PACK UP & GO ti gbilẹ bi owara-ọjọ tẹlẹ. Nibayii, ọmọbirin yii tun ti fọba le e pẹlu KO KAN WON, eleyii ti n se ajaabalẹ orin tuntun to ti gba gbogbo afẹfẹ bayii.

Adura mi ni wi pe: IYO ko ni baje, IYO ko ni dobu, awon omo araye o si ni da IYO merupẹ laelae. Asẹ 

 #HBDIYO

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment