Seun Egbegbe ati Toyin Aimakhu |
Ogbeni Seun Egbegbe to je oko ti Toyin Aimakhu fẹ nikete to kọ Adeniyi Johnson sile, eleyii ti yigi awon mejeeji tun pada tuka. Leyin ipinya yii ni Seun tun n leri wi pe, oju Toyin yoo ja. Sugbon o jẹ ohun iyalẹnu bi maanu naa se tun tọrọ idariji lowo obirin naa nigbangba.
"I hereby regret any inconveniences i might have caused Toyin Aimakhu. she's is an A-list actress, anyone who wants to do business with her should deal with her as a celebrated artist. I wish her the best..."
0 comments:
Post a Comment