Ogbeni Yanju Adegboyega, Igbakeji Olootu Alariya Oodua, lo n beere Ibeere Pataki yii lo won awon eniyan lori Facebook re.
Bi o tile je wi pe ko daruko Gomina Ajimobi, sugbon foto re lo fi han. Se bee lori bayii nipinle Oyo?
"Ibeere Pataki
Bawo la see so fawon odo asiko yi pe, eko dara? Nigba ti awon to kawe gboye ko ri nnkan kan se.
Sugbon, tawon agbero ati toogi n ri owo jaye."
E o wa kalo siluu Ayomoole, nibi ti Oloye. koseleri ti n se olori won. Kee wo bawon osise, paapaa oluko ti n jiya.
Sugbon, ti olori ijoba n fawon omo isota lowo se iwode atileyin fun un.
Mo kan n ronu jade ni o."
Bi o tile je wi pe ko daruko Gomina Ajimobi, sugbon foto re lo fi han. Se bee lori bayii nipinle Oyo?
0 comments:
Post a Comment