Iroyin agbọsọgbanu: Stephen Keshi ti ku o Olayemi Oniroyin 6/08/2016 10:01:00 am Ere Idaraya Edit Stephen Keshi A ti gbọ iku akọnimọọgba ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria nigba kan ri, Stephen Keshi. Ilu Benin ni okunrin naa ku si laarọ oni (08-06-16). Se ẹ ko gbagbe wi pe, laipe yii naa ni okunrin naa padanu aya rẹ. Ekunrere iroyin n bọ laipe. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni à...Anthony Joshua Oluwafemi to bẹru Iroyin agbọsọgbanu: Stephen Keshi ti ku o Reviewed by Olayemi Oniroyin on 6/08/2016 10:01:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment