Kèrè-kèrè bí ìdàgbà ìkókó la wo inú osù keje yìí, bí a ò bá ní go séyìn ìka owó fún ara wa, a lè so wí pé ògòrò àwon tí a jo
bèrè osù kefà kó lajo parí rè béè isé ire ti wa kó ló là wá, àánú Olódùmarè ni a rí gbà.
Bí a ti wá n lo nínú osù keje yìí, àánú Oba òkè ò ní ká kúrò láyé kóówá wa.
Gbogbo àwon tí wón wà lórí àketè àìsàn lákòókò yìí ni won ó gba ìwòsàn.
Ìfòkànbalè àti ìlosíwájú á jé ti gbogbo wa.
Òhaha ìyàn kò ní mú gbogbo wa nínú osù yìí àti jálè odún yìí láse Èdùmàrè.
Èrín la ó fi parí osu yìí o.
Orisun: Olùkó Èdè Yorùbá Arb (2016)
Amin lase Edumare. Osu yi a san wa si owo, omo, oro ati aiku bale oro.
ReplyDeleteE seun
DeleteAmin oooo ni agbara Olorun. E se mo dupe oooooo
ReplyDelete