Arakunrin kan to pe ara ni Frank lo n be Kemi Olunloyo, omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, lori ayelujara wi pe ko ba dara ti adelebo naa ba le gba ki oun ma la idi re bi aja.
Bakan naa lo fi ife han lati ma "kerewa" madaamu naa loganjo oru leyin to ba fi ahon la idi re tan bi igba ti omode n la oyin ninu abo.
Ohun to sele leyin igba naa ni bi Kemi se gbe bobo naa sojutaye.
"My Wikipedia profile reported I exposed men begging me for sex online. While most women feel offended and keep
quiet, I revealed the problem of male prostitution in Nigeria.
It is real. Today July 12th, I received a new one. Go to my Instagram @HNNAfrica to see the two new ones.
Since everyone wants proof of my Nigerian Journalism stories now, I begin posting screenshots. Be careful what you INBOX me.
#EndMaleProstitution
KOO"
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment