Latari olaju ati idagbesoke imo-ero, aimoye ipenija ni i koju awon ti won samulo ede Yoruba nilana ise ojo won.
Opo won ko mo bi won se le tunmo awon ede tuntun to n jeyo lagbo imo ero, ilera, oselu ati bee bee lo si ede Yoruba.
Sugbon ope pataki lowo awon onimo eda-ede (linguistics) ti won ko sinmi lati ri ona abayo si awon isoro yii.
Mo ri Jona kan eleyii ti T. A. Akanbi ati O. A. Aladesanmi lati Ifafiti ipinle Ekiti lati eka ti won ti n ko nipa imo eda-ede ati ede ibile Naijiria ko.
Ninu Jona ti won ko lodun 2014 yii ni won ti n se agbeyewo lilo awon ede ibile wa lori igbohunsafefe redio.
Ibe si ni mo ti ri awon ede tuntun ti awon onimo ti seda re fun irorun awon agbohunsafefe.
Eleekewa (10) ninu awon ede ti won toka re ni mo feran ju. O ya, e je ka lo yewo
1. Òdo-méjì-tógbé-ẹẹ́ jọ sáàrin - 080...GSM initial codes
2. Aṣọ-májámájá-ẹgbẹ́jọdá-àwọn-ọlọ́kadà - Reflexive jackets of the motorcyclist
3. Owó-sabanmu-òun-rèé - Bribery
4. Àwọn-àsẹ̀sẹ̀-jáde-ilé-ìwé-gíga - Fresh graduates
5. Lẹ́tà-iṣẹ́ -ìlú-yá/ìwe-ìsìnrú-ìlú-yá - Call-up letter (for Youth Service)
6. Ẹ̀ rọ-móhùnmáwòrán-abálédọ́gba - LCD/Plasma television
7. Ọkọ̀-òfurufú-agbérapá - Helicopter
8. Ẹ̀ rọ-ayára-bí-àṣá-àgbélétan - Laptop
9. Akẹ́kọ̀ó-ìdàbọ̀ - Part-time student
10. Akẹ́kọ̀ó-ìgbàyíláárọ́ - Sandwich student
12. Abẹ́rẹ́-kára-ó-le- Vaccine
13. Àrun-fòníkú-fọ̀la-n-de - Sickle cell disease
14. Ilé-ìgbìmọ̀-aṣojú-ṣòfin - House of Representatives
15. Ọkọ̀-gbókùú-gbáláàrẹ̀ - Ambulance
16. Eré-à-sá-gbọ̀n-rìrì - Marathon race
17. Ìdájọ́-ikú-lère-ẹ̀ṣẹ̀ - Death/capital sentence
18. Ìtàkùn-ayélujára-ojú-rẹ-dà-jẹ́-n-bá-ọ-dọ́rẹ̀. - Facebook
19. Ìyanṣẹ̀ -lódì-aláìní-gbèdéke-ọjọ́. - Indefinite strike
20. Ìlànà-tepo-níye-ó-pé-ọ - Downstream deregulation
21. Ìlàna-níní-owó-láì-fojú-rí i - Cashless policy
22. Ìbéèrè-èwo-nìdáhùn - Objective question
23. Bọ́ọ̀ lù-wòmí-n-gbá-sí-ọ - Penalty kick
24. Balógun-ẹgbẹ́-a-gbá-bọ́ọ̀ lù - Team captain
25. Káàdi-jáde-ní-pápá - Red card
26. Ẹ̀rọ-alágbèká - Handset
27. Ìwé àtẹ̀jíṣẹ́ - Text message
28. Titi márosẹ - Expressway
29. Ibùsọ̀dúró-n-yẹ̀-ọ́-wò - Checking point
30. Ẹrọ pọwó-pọwó - ATM
0 comments:
Post a Comment