Smiley face

Bayii niwon se sin Bukky Ajayi lojo odun itunu awe

Idile onigbagbo ni won bi si, sugbon nigba to ya lo gba esin musulumi. Lati igba naa lo ti n je Senabu gege bi oruko tuntun re.



Idi ni yii to fi je wi pe, ojo ti iya naa ku lojo kefa osu keje odun yii,(06/07/16), eleyii ti n se ojo odun itunu awe, naa ni won si Sanabu ni ilana isinku musulumi ododo.

Iboji to wa ni Yaba, ATAN cemetery, ni won si Bukky Ajayi si.

Ki oba Allah wo ola ipari osu alaponle ramadan ti iya naa jade laye, ko ba wa fori gbogbo ese re jin. Ko si ba wa fi ile ologo daa lola. Amin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment