E ma je ki n paro fun yin, awon isegun ati ibukun kan wa to je wi pe inu iyin Oluwa nikan ni idahun wa.
E ma gbagbe ogbon ojo ninu osu kesan-an odun yii [Sept 30. 2016] nibi ti odun iyin [Festival of Praise 2016] yoo ti ma waye.
Ilu Ibadan ni yoo ti waye ni oju ona Olorunsogo-akanran, eyin e sa ti duro ni ibudoko Idi Iroko. Ago mejo ale ni ipade yoo bere titi dilemo kelele.
Aimoye olorin emi ati ojise Olorun alaaye ni won on duro de ojo naa, nitori asaale agbara orin iyin ati idande ni yoo je.
Apostle Seye Akinlabi [Osan] ni Olorun n lo lati gbe akanse ipade naa kale. Eyin naa le pe Apostle, lati fi idi ododo mule: 08033502839.
O da mi loju wi pe temi ko ni soro se lodun yii. Amin

0 comments:
Post a Comment