Ogbeni Mutiu ti gbe si wa leti lori Yoruba Dun wi pe won ti fi Faithia Balogun je Atesinse Adinni niluu Ijebu-ode. Abo iroyin naa ni yii.
"Wọn ti fi Oye "Atẹsinse Adinni" Da Oṣere-birin Yoruba, Faithia Balogun lọla lana ni Ijebu, ni Ipinle Ogun.
Diẹ ninu awọn orẹ rẹ bi Dayọ Amusa, Kẹmi Afọlabi , Mojisọla Olaiya , Kẹhinde Roda ati Tayo Odueke ni won jọ sajọyọ pẹlu rẹ.Eku Oriire o. Oye A Mori O!"
0 comments:
Post a Comment