Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (15)

Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ
 
 Segun Ogunsola: Oga ooo ile aye yi ma le gan ni o, ekoo nla leleyi, ejowo eje ki a tete mo ibi ti o pari si, ki a lee mon ohun ti a maa so si.


Ifakolade Olayiwola:
Oro se ni wo,,,kale mo enito nfeni,,besini wipe akoriru eleyiri eru ni wonfi nda ba enitoba ni oro,,iwure temi si iwo arabinrin yini wipe oba mi odumare yogba o lowo awon alagbara aye tiwon femi a fi agbara owowon re o je,,olodumare losimanse idajo afeyin pin eran,,,yose idajo larin iwo ati oga re,,,se amin tabi asee nibi kibi ti obawa ki osi gbe ito remin..


Ajayi Modupe Ogungbenjo: O ga o..... Panpe eniyan le leyi o..... sugbon a o le mo bi a o se dasi oro naa nigbati e o pari oro yin, mo rò yin, e tete fi eyi to ku leta yin ranse.


Brave Tayo Harkenwale Biggy: Mo ni idaniloju wipe, asiko to lati bo kuro ninu idaamu re yi. Ki Olodumare ran wa lowo Amin


Kazeem Ariwoola Abimbola: Arabinrin lakoko naa e ku aforiti olorun eledumare yoo koyin yoo ninu idamu yii.sugbon ki oro yii le dun dasi,e gbiyanju lati je ki awon eniyan mo ibi to pari si.Alaafia ni fun yin.


Adedoyin Fatimah Ojugbele: Hmmm ti olorun ba ko e yo tan bo o le ko si inu iwe bi ayoka


Ogundijo Nureni Siyanbola: Emi mo wipe kosi oun to nibere tiki ni opin ko de si bi isoro seleto laye n bi eniyan o borire ni.Adura mi ni pe gbogbo wa a ni ri ogun alatako ori wa o sini gbabode


Oladepo Damilola Samuel: Too oo!! Nibi ti oro de duro yi,to ba sewo, iru igbese wo ni waa gbe?gegebi ona abayo


Gbemitosin Oje-Olubowale: Eyi gaa pupo o ki Olorun o gba wa lowo awon alagbara aye.

Princess Bukola Adegbodu: Kabete gbaa loro yi, sugbon ki lo wa sele oo?

Olaitan Aina Olatilewa: Ẹ jọwọ a n reti lẹta to ku o
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment