Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (7)



Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ
Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (7)

Abdullahi Bola: Se odao loju pe o ose rara? Ti o bati se nkan buruku si ile-se olorun o ko o yo o.Eniti a o le mu, olorun lan faa fun. Duro ko ma wo idajo olorun lori re.Sa mo daju pe olorun mbe pelu e.

Aderemi Saheed Olasile: Oun ti ko fe je ki awa okunrin mi ki feje ki iyawo wa si se ni abe enikeni ni yan,sugbon olorun ni kan lole gbeni bori iru unkan bayi,ebere si ni gba adura ki eledumare koko yin yo ni tori oleje esun ole lo fi kanyin lodo awon olopa,ki olorun oba ko koyin yoo

Abdulqadri Oba Saeed: Ha ha sungbn ma binu o se won tijuyin l ni? Oun temi ro pe ole so fun awn lpa nipe se ma pe ni obere file kan lw teni tigbe fun ole je ye lo so fun awn lpa lrun nikan lo le ko y kun fun adùa dáda afesona re kori inkankan se sini?sebi òbinrin ni ?oye kemo etan tele lo...jekin k nikan Loto nipe aki ti won de kasore sungbn oun tole fimu ni..bee kowa sope otigb pe ibo leti se watiso fun k bi gbogbo seje k yowa wole ba koto se kankan ni yowana dalapa toba wa kan tan owa loso oun tose fun nitoni ile'se gan gan pelu oun toda lapa i ree o

Ogunyele Omowunmi Kafayat: Haaaa aye ayee, aye manika ibase paye mose okunkun ni won bati dosupa loro, eledua oba adede nikan lole koni yo lowo aju nilo ti fowo ola gbani loju. O


Ogunrinola Ahmed Ayinla Medulla: Kayefi gba leyi je simi, Oba alatunse ni Edua, yio ko e yoo ninu rogbodiyan yii oooo.

Oyebamiji Kemi Wuraola: Haa! eyi ma gao,olorun tin gbani lojo isoro yio gba o,kosi ni ja o kule,tera mo adura.

Kolawole Azeez Baba Yoruba: Lodo temi teba le tunmo awon owe yii, yoo wulo fun yin: eni eegun le koma roju, tori bosen re ara aye lon re ero orun. Ohun ton tan lodun eegun. Akoda oro koda bi ada gbeyin.

Adegbaike Taofeek: Ni ti emi nse ni mi ba ro awon eniyan kaje ki arabinrin yi o pari oro re tan,ka ko eko ninu e ki a to ma wi ohun ti a fe so,e be mi si oluko iwe yi ni pe e ma je ko pe ju ki a to mo iperi oro yin,boje adura ni oro oga naa gba ni tabi epe nla.

Olúwáseun Bàbá Yorùbá Kómoláfé: ori yeye ni nku mogun taise lo po nibe,wo mi olabisi o ti yege lootito,jowo mase ro lokan re pe o se asise sugbon laipe ni waa ni aseyori,sugbon iya ojo ola ni oga yen san sile fun awon omo re.ire o.


Mary Olaide Possibility JP: Owe yoruba kan wipe~ a gbo ejo enikan da agba osika ni, a ko gbodo tori itara si oro oloro ki a wa jebi lodo Olorun, adura temi fun o nipe lehin gbogbo idanwo yi wa ri igbega lati odo Olorun Eleda re o, mo debi duro nitemi o,

Ifakolade Olayiwola: I hun kan nkan,,,,i hun kan nbe aguntan tomore sonu oni ihunkanbee,,,ihun kan nsele ni iju won kogbo leti le, bekedere ohunsele leti le ara etile nmun mora nii,,

Yoruba Heritage Culture: Kò sí olùgbèjà kan tó ju Olóun lo. Oba adájó nla alákeji! Ò gbèjà kí èrù ó tún ba oníjà. Yóó gbèjà a gbogbo o wa!

Sulaiman Hasanat Oladunni: Emi o ti leso ikankan afi ti e ba tusu desale koko


Ajayi Modupe Ogungbenjo: Jowo tete fi eyi toku leta yi ranse ki a le mo ibi ti a o doju adura ko.

Princess Dorcas Babatunde: Ti o ba dao loju wipe oko se inkan kan buruku nipa faili yi ti oga yi kan fe wa oro si e lese lasan ni ajiwipe oku okolorun .mebi olorun nikan lo le gbani lowo alagbara ton fowo agbara gbaniloju,oun kanna lolegbaniyan lowo kinihun aye ti ko fekeniyan rona lo .odami loju wipe yio gbao lowo alantaku oga re tofe takun dina re.idanwo ni gbogbo eleyi akuku dan jobu wo koda oju tire lo.wo mase kose mayi ipinu repada lori oro yi osi dami loju pe o bori dandan lolo eledua


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment