Gomina ipinle Oyo nigba kan ri, Victor Omololu Olunloyo ti rawo ebe si gbogbo awon eekan ilu ti omo re, Kemi Olunloyo, ti naka abuku si lori ayelujara.
Ninu atejade ti baba yii fi sita, o salaye wi pe "skonskon" diedie n yo omo naa lenu lati igba pipe eleyii ti awon si n be Olorun le lori fun iwosan.
Awon eniyan bi Obasanjo, Adeboye, Oyedepo ati Jide Kosoko wa lara awon ti baba naa rawo ebe si ninu leta re to ko jade.
Kemi Olunloyo, eni odun mejilelaadota (52), to fesun kan Jide Kosoko wi pe o n fi awon iyawo re soogun ti so tele ni awon igba kan ri wi pe, oloogun paraku ni baba tobi oun naa lomo.
Home / Uncategories / "Were diedie n jeun lori omo mi" Baba Kemi Olunloyo ti rawo ebe si gbogbo omo Naijiria
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Èyi jönïLóJú púpò
ReplyDelete