Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K. (9)

Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K. (9)
Royalty Adetola Ademola: Eni tafa soke to yido bori, b'oba aye o ri, Baba mi toda ofa ati ontafa nko?

Aderemi Saheed Olasile: Eledumare oba elesan yio san lesan iware.Oloto kan kole ku si ipoka lai lai

Adelana Daniel Oluwaseyi: Olorun Oba oloto ako ee yo

Badmus Adeola Akinola: Olorun a gbe e nija oooo a si fi oju asebi han

Ogunyele Omowunmi Kafayat: Hmmmmm. Oga o ko seyan mo, ka weni barin loku ile aye ile asan aye ayee aye anomo naye, olohun nikan lole ko ni yo lowo alaburu aye, ohun nikan lole koni yo lowo oni keeta eniyan ohun kan soso to ku bayi nipe ki ema be olohun oba ko gbeyin leke alabosi nitori pe o da mi loju gbangba gbangba pe oloto kan koni ku sipo ika, okunkun kan ko sini bori imole laelae, olohun oba tomo ati waye ojo to si mo atiwo orun ako o yo la se edumare. Ire o

Tunde Adio Ayedunjoyin: Asegbe o si laye..asepamo lo wa...ki Olorun ko e yo...!


Ajayi Modupe Ogungbenjo: Beni asegbe kan osi laye. Olorun esan yio gba esan re lara oga re naa lona ilopo mokanlelogoji(41).

Princess Dorcas Babatunde: Anpe oro yii lowe oman laro ninu wo eni ale mu olorun lakuku fa lelowo.oje fa oga re le olorun lowo kosi ma gbadura wipe keledua tete koe yo kin inkan to baje jina

Abdullahi Bola: Ti o ba mo right e, olopa o ni anfani lati da e duro leyin 24 hours. Wa adajo ta da ki ejo beere. Kini eri ti won ni pe iwo lo gbe faili.Aimoye charge & bail lawyers ti won o ri ise se ki won beeli e jade na.Olorun lon se idajo afeyin pin eran. Olorun lo mo olooto laarin eyin mejeji, boya iwo lo gbe faili pamo ki o fi se ika fun oga re tabi oga re lofi pamo lati fi ko e si wahala. Olorun lo ye o. Sibe na olorun yio ko e yo oooo.Ameen.

Bolatito Olabode: Hmmmmm,oba ti ngbe ni nija,keru o ba onija,yio gbe o nija o

Otunba Olajide Oguntimehin: Bi iro balo logun odun, ojo kan loti to adeba, Ati wipe agba to rofo ika, omo re aje nibe. Oun ti o pamo loju awa eniyan, kedere ni loju olorun oba. Bi oga lo paro mo e ni o' tabi iwo lo paro mo oga ile ise ni. Oro bibeli ni, A yoo bese baba wo lara omo, Lati iran kini titi de ikeyin. Sugbon oluwa yoo mu olotito lo si ipo ileri ni oruko jesu Amin?

Amoke Olushola: Ha?Eniyan.inu olorun baje ni tori wipe O.da eniyan.oluwa so bayi ninu iwe mimo wipe.ki.a.ma se danii lejo.Sugbon gbogbo iwa yio wu ti. ale ma wu.o ye.ki ama ranti.(ESE.MEFA)
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment