Tiwa: Ibadi mi ki sibe |
Bi o tile je wi pe enikeni ko gbo ohunkohun mo nipa oko Tiwa Savage to ko sile, sugbon ohun to daju ni wi pe, Tiwa ti tesiwaju ninu igbe aye alaafia.
Ilu Amerika ni sisi naa wa bayii ti n jaye bi Alaafin Lamidi.
Laipe yii ni Jaz Z tun gba wole sile ise orin re niluu Amerika.
Joojumo ni Tiwa n pawo wole bi sesefun, gbogbo igba ni i dara aso oge to gbamuse bi eye okin, bee lo gbayi nile ati loke okun bi isana-eleta.
Gbogbo epe ti Tunji Balogun gbese, ko si okankan ninu won ti Orisa oke tewo gba.
Ojo karun-un osu keji odun 1980 ni won bi Tiwatope Savage siluu Eko Oba Akinolu.
Igba to pari eko re ni University of Kent lo tun gba Berklee College of Music to wa ni California lo lati ko nipa orin kiko.
Olorun ti fun lomo, Balogun lo bi omo naa fun, Olorun fun lebun orin, ebu orin naa lo si fi n jeun.
Olayemi Oniroyin loruko mi, awon temi niluu Bombay ni won ma pe mi Emperor. Se e fe so wi pe e ko mo pe eniyan pataki lo je Emperor lorileede India ni?
0 comments:
Post a Comment