Smiley face

Ewe ati egbo Yoruba: fun Okun ati agbara

Boya eyin fe okun tabi agbara? Ohun ti e ma se ni yii.

E ra 7up kan tabi Sprite igo kan pere. E da iyo sibi ijeun si inu re pelu miliki olope kan pere.

Leyin eyi, e gbe lura.

Logan ni okun ati agbara yoo pada si ago ara yin. Te e si ma ta pon-pon.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment