Eid-el-Kabir: Ijoba Buhari ti kede ojo isimi fun awon osise Olayemi Oniroyin 9/07/2016 10:21:00 pm Iroyin Edit Ijoba apapo ile Naijiria ti kede ojo Aje ati ojo Isegun ti n bo, Sept.12 &13, gege bi ojo isimi lati fi yo ayo odun ileya Eid-el-Kabir ti n bo lona. Odun ayo ni gbogbo wa yoo se o. Amin Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Meji nínú àwọn olè Ofa tí de òpin ì...Boko Haram gbiyanju lati fẹ̀mí ṣòfò...Dangote tí bẹ̀rẹ̀ si ni ṣe moto Peu... Eid-el-Kabir: Ijoba Buhari ti kede ojo isimi fun awon osise Reviewed by Olayemi Oniroyin on 9/07/2016 10:21:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment