O daju wi pe odun ileya to n bo yii, ki i se ilu Naija ni
Saheed Osupa yoo ti se e pelu bo se bere iyide orin ka re si awon ilu
okeere. Ilu Jamani ni Matagbamole 1 ti koko bale, a ko si le so iye ojo
ti i yoo lo ni ilu naa ko to bo si ilu mii.
Sugbon sa, tijo tayo ni awon ololufee re fi wa pada Baba Sulia nikete to bale si orileede Germany.
0 comments:
Post a Comment