Smiley face

Ibadi yii lo n "kos turobu" lowolowo bayii lori ayelujara

Bi o tile je wi pe, won ma n dasa "kosohun taa mu waye, kosohun taa mu loorun", sugbon opo lo tile wa saye ti ko lohunkohun rara.

Iba Olorun, iba eeyan! Iru idi wo leyii?.

Yao Eudoxie Nice omo orileede Cotè d'ivoire ti n gbe ni Abidjan ti da wahala sile bayii lori ayelujara pelu awon foto akanilaya re to fon sori afefe. Iwadii Olayemi Oniroyin si ti fidi re mule wi pe, omobirin naa ti di gbajumo bayii lori ayelujara nipase oke erimo ti mbe leyin re
Kidi omo eniyan ta sita bi ebe isu, ko ri gelete bi eru okirika, ko wa le lowo bi ako okuta. Yeepa!

[Olayemi, soo ti fowo kan ni?]

Emi? Emi to je wi pe "born again" ni mi. Ijoba orun si ni afojusun mi.

Ki Oluwa ko ya mi si mimo, kosi se idarijin fun gbogbo okan to n ro irokuro pelu mi. Amin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment