Ope ni fun Olorun to mu wa ri osu tuntun. Ope fun awon ololufee wa ti won fe wa pelu awon asise wa.
Sebi won ni eda to ba monuro yoo mope da. Mo dupe ire gbogbo ati itewogba yin pata.
Gbogbo ire ti a ti n wa ninu odun yii yoo te wa lowo ninu osu yii. Oju wa yoo ri ire, eti wa yoo gbo ire, owo wa yoo si te ire pelu.
Awon eniyan yoo so ire pelu oruko wa. Won o fi ire ranse si wa lona jinjin ati nitosi.
Ire o ba wa sun, ire o ba wa ji. Ni agbara Olorun, aye wa yoo kun fun ire losu yii. Amin
www.olayemioniroyin.com/2015/11/iwon-ese-bata-kan-pere-e-kaabo-sinu-osu.html?m=1#more

0 comments:
Post a Comment