Smiley face

Wemimo pada domo tuntun a ri gbejo

Eniyan le fi owo ra aimoye ore ni awon akoko kan, eniyan si le fi owo ra okiki ni awon igba die, sugbon aimoye nnkan lo wa laye ti eniyan ko le fowo ra laelae.

Iru igbe aye ti eda eniyan n gbe, iwa ati ipa to ko fun idagbasoke awujo ki i pare kiakia lokan awon eniyan.

Oni ni ojo ibi ogbontarigi onise fiimu agbelewo, awo funfun ninu ise opolo, alase Wemimo Films Production, Wemimo Olu Paul.

Adura mi ko po rara, bi e ba lo igba odun laye, odun kan pere ni. Mo gbadura ire owo, alaafia, ayo, idera, igbega ati iyi repete.

#HappyDaySir #EniyanPataki
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment