Iya Ibadan ni opolopo mo o si, nigba ti awon kan a tun maa pe mi Iya Muse. Sugbon Chelsea Coker gan-an ni oruko re, ilu Toronto ni Canada si ni ibujoko re.
Omobirin naa si wa lara awon amuludun; alawada, adari ayeye, onisetiata ti ko se foworo ro seyin niluu Canada.
Lara awon fidio re apanilerin to gbajugbaja ti obirin naa se ni eyi to se afihan awon omo Naija ti won lo osu kan l'Amerika, ti won wa bere si ni fimu soro bi oyinbo nigba ti won ba pada dele.
Iya Ibadan ko leta si awon okunrin, leta naa ni yii:
0 comments:
Post a Comment