Arakunrin yii ni a gbo wi pe o pa ara re nipa pipokunso ninu ile kan ti won ko lowo ni agbegbe Aboru niluu Eko. Iwadii si n lo lowo nipa ohun to mu okunrin pa ara re. Sugbo aheso ti a gbo ni wi pe, ibanuje airina airilo lo mu okunrin naa seku pa ara re. Ekunrere iroyin nbo laipe.
0 comments:
Post a Comment