Ooni Ogunwusi Adeyeye naa ko gbeyin ninu irun yidi to waye lana pelu bo se darapo mo awon musulumi lati kirun Yidi.
Gege
bi e ti mo oro awon omo Naija, awon kan gbe oriyin fun un gege bi emi
ife ati isokan to n fihan nigba gbogbo. Nigba ti a ri awon kan ti won so
awon oro kobakungbe si oko Wuraola.
Sugbon
gege bi a ti ma n gbo lati igba iwase, oba ba le ohun gbogbo ni, gbogbo
aye si ni t'oba n se. Oba o lesin, gbogbo esin loba n se.
0 comments:
Post a Comment