Agbara ko lowonini, akosile eda ni yoo pada leke ninu irin-ajo eda ni dunniyan.
Awo tuntun Reekado Banks, Spotlight, ti wo agbo awon awo-orin to lokiki ju lagbaye bayii.
Aseyori nla naa dabi oke talagbara gun ti ko ri gun, sugbon t"Omo Olorun" Reekado gun lai sinira. Iyanu Nla!
Odun 1994 ni won bi Ayoleyi Solomon siluu Eko Oba Rilwan Akiolu. Yunifasiti ilu Eko lo si ti kaye gboye pelu sabuke nla to joju.
Ati kekere lorin ti n so si i lokan, sugbon iwadii Olayemi Oniroyin fidi re mule wi pe, odun 2008 gan-an lo mu ise orin gege bi ise asela. Aimoye aseyori lo si ti te e lowo lati igba naa titi doni
Boya eyin ko ti ni awo-orin tuntun Reeky to pe ni Spotlight lowo, o ya, e je ka lo Download e ni kiakia.
Olayemi Oniroyin fi asiko yii ki Reekado fun aseyori nla, eleyii to je wi pe, OLUWA NI'kan lo le se iru e feda.
#Kongiratulasan
0 comments:
Post a Comment