Smiley face

Ayantunde Anselm Ramacher : Omo ilu Germany ti n fi ilu bata powe Yoruba

Alejo pataki mi lori eto GBEDEMUKE lose yii ni Ogbeni Ayantunde Anselm Ramacher, omo bibi ilu Jamani (Germany).

Yato si wi pe Ogbeni Anselm Ramacher je ojulowo ayan to mo tifun-tedo awon ilu ile Yoruba, o le ko; o si tun le so ede Yoruba pombele.

Ojo Satide to n bo yii ni ipade wa,15-10-2016, ni aago mesan-an aaro, lori itakun agbaye www.radiodiaspora.com.ng

E fi sokan!

@OlayemiOniroyin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment