Ọpọ awon omo Naija lo wa loke okun ti won ba Naijeria loruko jẹ. Ise ibi ti won se lo sọ wa di orileede buruku lode agbaye.
Sugbon bi a se ri awon ti won bajẹ bẹẹ naa ni a ri awon ti won gbe e laruge. Inu awon ti won gbe e laruge ni Clement Shola Ogundipe ti gbogbo eniyan mo si Clemso wa.
Lọjọ ayajo ọjọ ominira Naijeria to koja yii ni Clemso ju orin tuntun sori afẹfẹ lati ilu Finland to wa lati fi kilọ iwa bajẹ eleyii to gbilẹ lawujo wa.
Bakan naa, ko sai gba won niyanju lati mu iwa ọtun wọ ki itesiwaju le de ba awujo wa. ORO lo pe akọle orin naa.

Eleyii kọ ni orin akọkọ Clemso, o ti kọ aimoye orin sẹyin. Bẹẹ si ni laakaye rẹ nipa agbekale orin ko bintin. Mo ti pinnu lati
gbe Clemso wa si ori ọkan lara awon eto ori radio mi, GBEDEMUKE.
Lori
eto yii lati mọ nipa eni ti Clemso jẹ ati awon nnkan to nise pelu orin
rẹ ati ilu Finland to fi se ibujokoo.
Ẹ pade mi lọjọ Satide ti n bọ yii [8-10-2016] ni deede ago mesan-an aaro (9.00GMT) lori ikanni www.radiodiaspora.com.ng
E le fi awon ibeere yin ranse si ori +2348032394964 tabi yemoford@mail.com saaju ọjọ naa.

ORO by Clemso Download
0 comments:
Post a Comment