Awon Yoruba bọ, won ni a ki i fi eniyan joye awode ko ma le gbadiyẹ. Ti a ba n pe eniyan ni Oga Nla, o gbọdọ maa se bi ọga nla ni.
Eleyii ti Pasuma tun ju yii fi ye wa wi pe, OGA NLA ni won pe ni BOSS looto. Ibi gbogbo lo gba alagbara, iru orin wo lo tun wa ku ti Pasuma ko ti ko?
CHANGE ni eleyii, o ta lenu. Ye wo!
0 comments:
Post a Comment