Bi mo ba ri onise opolo to fakiki, emi ki i foju pa won re. Bi mo ri onilaakaye eda, emi ki i teju won mo erupe ile. Ti mo ba reni ti Edua oke fun lebun to lekenka, kilode ti mi o ni gbe "tuale" fun un?
Ise opolo Akin pegede!
Akole ise ona yii lo pe ni: "Work hard & Smart", eleyii to n se afihan Olamide Baddosneh.
Odindi ojo merinla (14) ni omokunrin naa lo gba oun lati pari ise naa.
Ka ma paro, ise eleyii ta lenu.
Orisun: Akin Myboy/Facebook
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment