Aimoye eranko nla lo wa ninu igbo, sebi o wu Edumare lo de kinihun lade oba. Aimoye oniroyin alaso oge lo po nile yii, sugbon ojulowo won ni ko pe meji; Ronishratis loga nla, Omidan Aderonke Akinkuade ni Oba oke fun se.
Oni lojo ibi omidan onise-opolo, Aderonke omo Akin fakoyo!
Oni lojo ibi oludasile Ronishratis,
Aderonke omo Akin gbayi pupo!
Oge sise ti dowo, ewa oge asiko ti damuyangan lawujo. Ise re ko ni ba je, ewa re ko si ni dobu. Ase!
Happy Birthday
www.ronishratis.blogspot.com
0 comments:
Post a Comment